Ferdinand Adams
Ìrísí
| Ferdinand Adams.jpg | |||
| Personal information | |||
|---|---|---|---|
| Orúkọ | Ferdinand Eloy Adams | ||
| Ọjọ́ ìbí | 3 Oṣù Kàrún 1903 | ||
| Ibi ọjọ́ibí | Berchem, Belgium | ||
| Ọjọ́ aláìsí | 25 December 1985 (ọmọ ọdún 82) | ||
| Ibi ọjọ́aláìsí | Anderlecht, Belgium | ||
| Playing position | Striker | ||
| Youth career | |||
| 1918–1921 | Anderlecht | ||
| Senior career* | |||
| Years | Team | Apps† | (Gls)† |
| 1921–1933 | Anderlecht | ? | (?) |
| National team | |||
| 1924–1930 | Belgium | 23 | (9) |
| * Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). | |||
Ferdinand Eloy Adams(ọjọ́ kẹta oṣù karùn-ún ọdún 1903 – ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1985) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àgbáyé ará Belgium tí ó gbá bọ́ọ̀lù gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù fún Anderlecht.. Adams gba góòlù mẹ́sàn-án ní ìfarahàn mẹ́sàn-án fún ẹgbẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Belgium, ó sì gbá bọ́ọ̀lù ní ìdíje Ife Agbaye ti FIFA ti ọdún 1930.
Àwọn ìjápọ̀ òde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ìròyìn Anderlecht (in French)
- Ferdinand Adams
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Page Àdàkọ:Reflist/styles.css has no content.